Infinity - Aye Ole Lyrics

Infinity - Aye Ole Lyrics

 

Intro
Hmmmm
Omo eniyan
F'eti si
Oro agba, bi o she l'owuro
A she lowo ale

Verse 1
Bowun ko pe titi, iya aye wa o n bo wa d'opin
Aimola eda lo mu eda saniyan ra
Olorun ti seleri, oro baba ko ni ye
Aini gbaggbao lo mu eda raropin
Bi okun n fo
Ti osa n sa
Otito wa laaye
Igbabo ni orisun ohun gbogbo

Chorus
Oh Hu hu hu
Aye yi ko male
Aye ole fun eni to ni gbagbo pe aye ole
Oh Hu hu hu
Aye yi ko male o
Aye ole fun eni to ni gbagbo pe aye ole
Hu hu hu
Aye yi ko male
Aye ole fun eni to ni gbagbo pe aye ole
Oh Hu hu hu
Aye yi ko male o
Aye ole fun eni to ni gbagbo pe aye ole

Verse 2
Oni suuru, ape koto je, koni jebaje
Ai mani suuru lo n mu are eni bo wa debi
F'oju re womi ore, k'Oluwa le foju re wo e
Abiku ti d'abiye ninu aye mi
Oni suuru, ape koto je, koni jebaje
Ai mani suuru lo n mu are eni bo wa debi
F'oju re womi ore, k'Oluwa le foju re wo e
Abiku ti d'abiye ninu aye mi

Repeat Chorus

Verse 3 5x
Ha ha ha
Aye re ko ma ni le
To ba ba Olorun rin, o sho ri re

Bowun ko pe titi, iya aye wa o n bo wa d'opin

Comments

Popular Posts